Profile User Icon

Overview

Oyèwọlé Ògúnwálé, an influential Yoruba author and media professional, was born in the ancient town of Ìwó in 1949, into the respected Òkéyẹ̀lú family. He was the son of Chief Samuel Ìṣọ̀lá Ògúnwálé and his wife, Ṣubúọ́lá Ògúnwálé.

His educational journey began at D.C. School Àjàngbàlá Ẹlẹ́hàá, Ìwó, after which he proceeded to Ìwó Grammar School. He later attended Odùduwà College, Ilé-Ifẹ̀.

Ògúnwálé taught for several years at Baptist Secondary Modern School, Ìwó, before joining the West African Examinations Council (WAEC) in Kano in 1976.

In 1977, he enrolled at the University of Lagos and completed his cultural studies in 1979. That same year marked his entry into broadcasting as a Yoruba-language journalist with the Nigerian Television Authority (NTA) in Lagos. In 1981, he was transferred to the NTA Ìkẹjá branch, Tejuosho station. He would later be associated with the Oyo State Television Corporation (BCOS), where his work championed Yoruba culture and language.

Ògúnwálé’s literary output includes the notable dramatic work Iyán Ogún Ọdún.

Profile User Icon

Author Profile

Full Name: Oyèwọlé Ògúnwálé (born 1949)
Place of Birth: Ìwó, Ọ̀ṣun State, Nigeria
Language of Writing: Yorùbá
Occupation: Writer, Teacher, Broadcaster

Brief Bio:

A bí Ọ̀gbẹ́ni Oyèwọlé Ògúnwálé ní ìlú Ìwó ní ọdún 1949 ni agbo ilé Òkéyẹ̀lú. Àwọn òbí rẹ̀ ni Olóògbé Olóyè Samuel Ìṣọ̀lá Ògúnwálé, Ẹ̀kẹ́rin ìlú Ìwó (1949–1974) àti Ìyáàfin Ṣubúọ́lá Ògúnwálé.

Ọgbẹ́ni Oyèwọlé Ògúnwálé jáde ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ni D. C. School Àjàngbàlá Ẹlẹ́hàá ní Ìwó. Lẹ́yìn náà ni ó kẹ́kọ̀ọ́ síi ní Ìwó Grammar School, Ìwó. Ó tẹ̀ sí iwájú nínú ẹ̀kọ́ ọ rẹ̀ ní gbà tí ó bọ́ sí Odùduwà College ní Ilé-Ifẹ̀, níbi tí ó ti ka ẹ̀kọ́ ìwé méjìlá rẹ̀.

Ọ̀gbẹ́ni Oyèwọlé Ògúnwálé ṣe iṣẹ́ Olùkọ́ fún ọdún díẹ̀ ní Baptist Secondary Modern School, Ìwó kí ó tó lọ gba iṣẹ́ ni W.A.E.C. ti ẹka ìlú Kano ní ọdún 1976.

Ọdún 1977 ni Ọ̀gbẹ́ni Oyèwọlé Ògúnwálé dà ara pọ̀ mọ́ ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa àṣà, ti Yunifásitì ìlú Èkó. Ibẹ̀ lọ́ wà di ọdún 1979.

Ní ọjọ́ kìíní oṣù kejìlá ọdún un 1979 ni ó di oníròyìn ède Yorùbá ní ilé iṣẹ́ tẹlifíṣàn àpapọ̀ ní Èkó. Ọdún un 1981 ni wọ́n gbé e lọ sí ẹ̀ka tẹlifíṣàn àpapọ̀ ti Ìkẹjá, tó wà ní Tẹ́júoṣó ní Èkó. Ọ̀gbẹ́ni Ògúnwálé tún ṣiṣé ní Tẹlifíṣàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Iyán Ogún Ọdún

Major Works


Biographical Note: Further details about the author are currently unavailable.

Reference
Adedeji, Ridwan. (2025). Oyèwọlé Ògúnwálé. Litireso Yoruba. https://litiresoyoruba.com/oyewole-ogunwale/ (Accessed on October 28, 2025 at 21:10)

Similar Entries

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.