Àkópọ̀ Ìtàn Eégún Aláré láti ọwọ́ọ Láwuyì Ògúnníran
In this post, we shall examine the summary of Eégún Aláré by Láwuyì Ògúnníran; the story of Ọ̀jẹ́làdé, a humorous masquerader.
In this post, we shall examine the summary of Eégún Aláré by Láwuyì Ògúnníran; the story of Ọ̀jẹ́làdé, a humorous masquerader.
Eégún Aláré jẹ́ ìwé ìtàn àròsọ tó sọ ìtàn Ọ̀jẹ́làdé, to jẹ́ eégún aláré, àti àwọn itú tó pa. Olóògbé Láwuyì Ògúnníran ni ó kọ ìwé náà.