Overview
Àwọn Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n by Adeboye Babalola is a collection of 27 lineage praise poems of Yoruba people. This book is an expanded edition of the original, “Awon Oriki Orile” first published in 1966. The author later added 11 more lineage praise poems to the collection in 1999. This is why the title of the book was changed to Awon Oriki Orile Metadinlogbon (Twenty-seven Lineage Praise Poems).
There are a lot of lineage praise poems that showcase the origin, behaviours, culture and traditions of the Yoruba ancestors in the book. To make the poems easier to understand, the author included explanation sections where the meaning of complex words and phrases in the praise poems are explained in detail.


Book Profile
- Title: Àwọn Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n
- Author: Adébóyè Babalọlá
- Genre: Oríkì (Praise Poems)
- Year of Publication: 1999
- Publisher: LearnAfrica PLC
- Number of Pages: n/a
- Structure: 27 praise poems
- ISBN: 978 026 029 3
- Edition: Second Edition
Availability
- Available Format: Print (Paperback)
- Where to Borrow: n/a
- Where to Buy: Ẹ lè rí ìwé náà rà ni àwọn ilé ìtàwé jákèjádò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Brief Description:
Àwọn Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n láti ọwọ́ Adébóyè Babalọlá jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn oríkì orílẹ̀ mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n pàtàkì gẹ́gẹ́ bí àkọlé rẹ ṣe fi hàn. Ìwé yìí jẹ́ àtúnṣe ìwé tí Ọ̀jọ̀gbọ́n Adébóyè Babalọlá tí kọ́kọ́ gbé jáde ní ọdún 1966 tí àkọlé rẹ̀ sì ń jẹ́ Àwọn Oríkì Orílẹ̀. Ònkọ̀wé náà fi oríkì mọ́kànlá kún èyí tó ti tẹ̀ ṣáájú nígbà tí ó ṣe àtúnṣe ìwé náà ni ọdún 1999. Èyí sì ni ìdí tí wọ́n fi yí orúkọ ìwé náà padà sí Àwọn Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n.
Àwọn oríkì oríṣiríṣi sodo sínú ìwé yìí. Ṣé tí ìran Olúfè ni ká sọ ní tàbí ìran ìrènímògún àbí ìran Arẹ̀sà? Gbogbo àwọn oríkì ìran tí ó ń ṣàfihàn àwọn ìtàn, ìwà, ìṣe àti àṣà àwọn baba-ńlá àti ìyá-ńlá àwọn orírun kọ̀ọ̀kan ló péjúpésẹ̀ sínú ìwé ọ̀hún. Ònkọ̀wé náà tún fi àwọn ọ̀rọ̀ àlàyé tó ń ṣàlàyé ìtumọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ tó farasin nínú àwọn oríkì orílẹ̀ kọ̀ọ̀kan.
Also by Adébóyè Babalọlá
- Àkójọpọ̀ Àlọ́ Ìjàpá (Apá Kejì)
Alternative Spellings
Here are the alternative spellings, mostly anglicised, of the keywords, having been stripped of their diacritic marks:
- Awon Oriki Orile Metadinlogbon
- Adeboye Babalola
- Awon Oriki Orile Metadinlogbon by Adeboye Babalola