Ìjàpá Tìrókò Ọkọ Yánníbo
|

Àgbéyẹ̀wọ̀ Ìjàpá Tìrókò Ọkọ Yánníbo láti ọwọ́ọ Ọlágòkè Òjó

Ìjàpá Tìrókò Ọkọ Yánníbo jẹ́ àkójọpọ̀ ogún ìtàn àròsọ kéékèèké tó wá láti ọwọ́ọ Ọlágòkè Òjó, tí Learn Africa Plc sí kọ́kọ́ gbé jáde ní ọdún un 1973.